Ademola Adeleke
Ademola Adeleke | |
|---|---|
| 10th Governor of Osun State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
| Ó gun orí àga 27 November 2022 | |
| Deputy | Kola Adewusi |
| Asíwájú | Gboyega Oyetola |
| Senator for Osun West | |
| In office 2017–2019 | |
| Asíwájú | Isiaka Adeleke |
| Arọ́pò | Adelere Adeyemi Oriolowo |
| Àwọn àlàyé onítòhún | |
| Ọjọ́ìbí | Ademola Nurudeen Adeleke 13 Oṣù Kàrún 1960 |
| Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party |
Ademola Nurudeen Jackson Adeleke (Ti abi ni ojo ketala osu karun ni odun 1960) je oloselu ati onisowo Naijiria kan, eni ti o ti se gomina ipinle Osun lati odun 2022.[1] Òun ni Seneto tó sójú agbègbè Senatorial Osun-west lati odun 2017 si odun 2019. O wà lati ìdílé Adeleke ni ilu Ede ni Ipinle Osun . O dije nínú idibo gomina ipinle Osun lodun 2022 labẹ ẹgbẹ oselu Peoples Democratic Party, o si bori Gómìnà to wà níbè, Adegboyega Isiaka Oyetola ti ẹgbẹ oṣelu APC ti o jáwé olubori nínú ibo gomina ipinle Osun lodun 2018 . [2]
Ẹkọ
Adeleke bere ẹkọ ako bere ni Methodist Primary School, Surulere Lagos State ki o to pada Si ilu Oyo State lati tẹsiwaju ninu eko ni Nawarudeen Primary School, Ikire. Ati ile iwe ẹkọ gíga Seventh Day Adventist Secondary School, Ede ni ipinle Oyo lati ka iwe ni Ede Muslim Grammar School Ede, nibiti ti ọ ti pari secondary school education lati lọ ka iwe ni ilu United States.[3] o fi ilu Naijiria la le lati lọ ka ìwé pẹlu awon egbon re méjì ni United States of America.[3]ile iwe ẹkọ gíga ni Jacksonville State University,[4] Alabama ti ọ sí gbọye degree. nipa odaran àti oṣelu.[5]
Awon ise
Ise aladani
Adeleke je onisowo ati alakowe, o sise gege bii alakoso agba ni ile-ise iponti Guiness lati odun 1992 si odun 1999 nibiti ikan ninu awon akegbe re si je Oga-ogun Theophilus Danjuma;[3] o tun je alakoso agba ni ile-ise aburo re, Pacific Holdings Limited lati odun 2001 titi di odun 2016.[4] ki o to dara po mo Pacific Holdings Limited, o ti sise ni ile ise ifi nnkan ranse ti a mo si Quiksilver Courier Company ni ilu Atlanta, Georgia ni orile-ede Amerika gege bi agba ise se ni odun 1985 si odun 1989. o tesiwaju ri ise si ile-ise awon nnkan oloorun adidun ti a mo si Origin International LLC ni ilu Atlanta ni Georgia ni orile-ede Amerika gege bi igbakeji alakoso agba patapata lati odun 1990 si odun 1994.[5]
Itokasi
- ↑ "Gov. Ademola Nurudeen Jackson Adeleke Achievements – Osun State Official Website". Osun State Official Website – Osun – State of the Living Spring. 2023-06-12. Retrieved 2023-06-12.
- ↑ "Adeleke get 17 out of 30 local goment areas to win Osun govnorship election". https://www.bbc.com/pidgin/tori-62189734.
- ↑ "Ademola Adeleke's School Certificate Scandal And Other Things To Know About Osun Governor-elect | Sahara Reporters". saharareporters.com. Retrieved 2022-09-22.
- ↑ "How I built multi-million dollar business in US, Senator Ademola Adeleke". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-19. Retrieved 2022-02-24.
- ↑ Admin. "Personality of the Week: Ademola Adeleke". Sun News Online. Retrieved 27 January 2019.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.